Awọn ti a fọrọ wa lẹnu wo ko fi ero wọn pamọ rara nipa ohun ti ijọba ilẹ Naijiria nfi owo iranwọ epo se.