Bi ọkọ tó ń sáré ṣe bá ara rẹ lórí àjà ilé onílé kàn rèé
Bi ọkọ tó ń sáré ṣe bá ara rẹ lórí àjà ilé onílé kàn rèé
O daju pe awakọ naa ko bikita nipa awọn awakọ mii to wa loju ọna to fi n wa naa lọna ti ko boju mu.
Imọran atata fun awọn awakọ lasiko yii nitori ohun gbogbo lo n fẹ suuru.