UNILAG TV: 'Isẹ yoo bẹrẹ laipẹ'

ile eko giga fasiti ti ilu eko je alakoko ninu awon fasiti orile ede Naijiria ti yoo gba iwe ise amohun-maworan Image copyright UNILAGTV/TWITTER
Àkọlé àwòrán Ile ẹkọ giga fasiti ti ilu eko jẹ alakoko ninu awon fasiti orile ede Naijiria ti yoo gba iwe ise amohun-maworan

Oludari ile-ẹkọ giga ti Eko, Ọjọgbọn Oluwatoyin Ogundipe sọ pe Ile isẹ amohun-maworan ti ile-ẹkọ giga ti ilu Eko yoo bẹrẹ iṣẹ laipẹ.

Ọjọgbọn Ogundipe sọ fun BBC Yoruba wipe awọn alakoso ile-ẹkọ giga naa ti bẹrẹ isẹ ni pẹrẹwu lat se eto ti o tọ ti o si peye fun awọn akẹkọ ile ile giga naa.

Ninu ifọrọwanilẹnuwo, o salaye wipe ile ẹkọ giga naa ti gbaradi lati wo ọrọ igbohunsafẹfẹ finni-finni lati ko awọn eniyan jankan-jankan ti wọn ni imọ nipa rẹ jọ fun isẹ ti o peye fun awọn akẹkọ.

Ẹ gbọ fọran naa nibi:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionUNILAG TV: 'Isẹ yi o bẹrẹ laipe'