UNILAG TV: 'Isẹ yi o bẹrẹ laipe'

UNILAG TV: 'Isẹ yi o bẹrẹ laipe'

Ọjọgbọn Ogundipe sọ fun BBC Yoruba wipe awọn alakoso ile-ẹkọ giga naa ti bẹrẹ isẹ ni pẹrẹwu lat se eto ti o tọ ti o si peye fun awọn akẹkọ ile ile giga naa.