Ọmọ ẹgbẹ APC faramọ iwoye Obasanjo

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionLori lẹta Obasanjọ

Olori osisẹ lọofisi gomina ipinlẹ Oyo, Ọmọwe Gbade Ojo wipe oun faramọ ọpọ ohun ti Obasanjọ sọ ninu lẹta Buhari.