Ọmọ ẹgbẹ APC tako Ọbasanjọ lori iwe to kọ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọmọ ẹgbẹ APC tako Ọbasanjọ lori iwe to kọ si aarẹ Buhari

Ọmọwe Gbade Ojo, tii se eekan kan ninu ẹgbẹ oselu APC nipinlẹ Ọyọ ti tako Oloye Olusẹgun Ọbasanjọ lori iwe to kọ si aarẹ Muhammadu Buhari. O ni, ko yẹ ko gbe iwe yi fun gbogbo aye lati ka, amọ o yẹ ko fi sọwọ si aarẹ Muhammadu Buhari ni bonkẹlẹ ni.