Ajọ SERAP sọrọ lori owo ifẹhinti awọn oloselu kan
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ajọ SERAP bu ẹnu ẹtẹ lu owo ifẹhinti f'awọn oloselu

SERAP: "Owo ifẹhinti ko tọ si ẹni ti o sisẹ gẹgẹ bii gomina ilu fun patapata ọdun mẹjọ"