EFCC: Babachir Lawal bọ ninu ihamọ

Àwòrán Ìròyìn Yàjóyàjó

Akọwe ijọba ilẹ Naijiria nigbakanri, ọgbẹni Babachir Lawal bọ ninu ihamọ EFCC. Ogbẹni Lawal ti wa ni ahamọ fun ifọrọwanilẹnuwo lati ọjọru.

A n se akojọpọ ẹkunrẹrẹ iroyin yajoyajo lọwọ, a o maa gbe ẹkunrẹrẹ iroyin naa sori atẹ iroyin wa laipẹ. Ẹ jọwọ, ẹ tun oju opo iroyin yi yẹwo, ki ẹ lee ri ẹkunrẹrẹ iroyin ọtun laipẹ.