Bawo ni iforukọsilẹ awọn oludibo se nlọ pẹlu INEC?

Bawo ni iforukọsilẹ awọn oludibo se nlọ pẹlu INEC?

Eto iforukọsilẹ nlọ lọwọ bayi ni awọn ijọba ibilẹ pẹlu ajọ ti o n se akoso idibo ni orilẹede yi (INEC).

BBC Yoruba se abẹwo si ijọba ibilẹ Eti-Osa ni Falọmọ nilu Eko.