Olorin wo ni yoo gba ami ẹyẹ Grammy ni America?

Image copyright BBC/Getty Images
Àkọlé àwòrán Awọn olorin yoo figagbaga lorilẹede Amerika

Igba ọgọta niyi ti wọn yoo se ayẹyẹ ami ẹyẹ to ma n waye lọdọọdun fun awọn olorin oniruuru ni orilẹede Amerika. O jẹ igba akọkọ lati ọdun 2003 ti ayẹyẹ yii ko ni waye ni Los Angeles ti o ti jẹ ile ayẹyẹ yii lati ọdun 2004.

Grammy Award jẹ idalọla ti wọn ma n se lati gboriyin fun ipa ti awọn olorin ti ko. Lọdọọdun, ayẹyẹ yii ma nsafihan orin awọn gbajugbaja olorin.

Wọn se akọkọ ayẹyẹ idalọla Grammy ni ọjọ kẹrin, ọdun 1959 lati mọ riri isẹ orin awọn olorin eyi ti wọn se ni ọdun 1958.

A Grammy Award (stylized as GRAMMY, originally called Gramophone Award), or Grammy, is an award presented by The Recording Academy to recognize achievement in the mainly English-language music industry. The annual presentation ceremony features performances by prominent artists, and the presentation of those awards that have a more popular interest. It shares recognition of the music industry as that of the other performance awards such as the Academy Awards (film), the Emmy Awards (television), and the Tony Awards (theater).

Ikọkandinlọgọta ayẹyẹ yii waye ninu osu keji ọdun 2017 lati da awọn olorin to fakọyọ ju laarin osu kẹwa ọdun 2015 si osu kẹsan ọdun 2016 lọla ni ibudo Staples Centres ni Los Angeles.

Ti ọdun yii waye ni ọjọ kelidinlọgbọn osu kini, ọdun 2018.

Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Gbajugbaja olorin, Lady Gaga naa yoo kọrin nibẹ

Lara awọn olorin ti awọn eniyan nreti lati dije fun idalọla Grammy

 • Awaken, My Love! - Childish Gambino aka Donald Glover
 • 4:44 - Jay-Z
 • Damn - Kendrick Lamar
 • Melodrama - Lorde
 • Song of the year
 • That's What I Like - Bruno Mars
 • Despacito - Luis Fonsi and Daddy Yankee feat Justin Bieber
 • Issues - Julia Michaels
 • Redbone - Childish Gambino
 • The Story of OJ - Jay-Z
 • Humble. - Kendrick Lamar
 • Shape of You - Ed Sheeran
 • Love So Soft - Kelly Clarkson
 • Praying - Kesha
 • Million Reasons - Lady Gaga
 • What About Us - Pink
 • Stay - Zedd & Alessia Cara
 • Feel It Still - Portugal The Man
 • ÷ (Divide) - Ed Sheeran
 • Kaleidoscope EP - Coldplay
 • Lust for Life - Lana Del Rey
 • Evolve - Imagine Dragons
 • Rainbow - Kesha
 • Joanne - Lady Gaga
 • Traditional pop vocal album
 • In Full Swing - Seth MacFarlane
 • Nobody But Me (Deluxe Version) - Michael Bublé
 • Triplicate - Bob Dylan
 • Wonderland - Sarah McLachlan
 • Cola - Camelphat and Elderbrook
 • Andromeda - Gorillaz feat Dram
 • Tonite - LCD Soundsystem
 • Dance/electronic albumMigration - Bonobo

Ati bẹẹ bẹẹ lọ

Related Topics