Iba Lassa: Wo awọn ọna ti o le gba dena arun naa

Obirin ti o n ta garri nilu eko Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Ma si garri sile ni ita gbangban lati dena iba ọrẹrẹ

Lorilẹede Naijiria awọn eniyan ti o ti padanu ẹmi wọn sọwọ iba rẹrẹ ti le ni ogun ninu odun 2018, gẹgẹ bi ajọ ti o n se amojuto arun se so.

Ipinlẹ mẹtala ni iba yi ti sẹyọ lọwọlọwọ, sugbọn awọn ona ti o rọrun wa ti a le gba dena rẹ - wo fọnran BBC Yoruba yi lori ikanni Facebook fun awọn ona naa.