Ayanbinrin Ara fi ilu kọrin ibilẹ Naijiria

Ayanbinrin Ara fi ilu kọrin ibilẹ Naijiria

Ẹnu ati awọn ohun elo orin bii duru ati fere ni awọn eeyan fi nkọ orin ibilẹ orilẹede Naijiria saaju akoko yii.

Ni bayii, gbajugbaja obinrin agbasa ga nni, ti ọpọ eniyan mọ si Àrà, ti wa fi ilu gangan kọ orin idanimọ orilẹede Naijiria bayii.

Ara se eyi ni ile Oodua, tii se aafin Ọọni ilẹ ifẹ.