Àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìwòsàn gbé ọmọ Ọbà fún Ọ̀ṣun!

Àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìwòsàn gbé ọmọ Ọbà fún Ọ̀ṣun!

Idile meji kan ni orilẹ-ede India kọ lati da awọn ọmọkunrin meji ti wọn sigbe funra, pada fun awọn obi wọn lẹyin ọdun kẹta ti asise naa waye.

Ọjọ kan ni wọn bi awọn ọmọ naa, ni asiko kan naa ni àwọn iya wọn n rọbi eyi to jẹ ki àsise naa seese ko waye.