Awọn Oludari ile ẹkọ giga fasiti Modibbo gbe agadangodo s'ilẹkun

Awọn Oludari ile ẹkọ giga fasiti Modibbo gbe agadangodo s'ilẹkun ile ẹkọ naa lẹyin iku ọmọkunrin kan lori ija ẹlẹsinmẹsin.