Alaye lori bi ilẹkun baalu se fo yọ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Bayo Sanwo salaye lori ilẹkun baalu Dana to fo yọ nilu Abuja

Ọpọ ero to wa inu baalu Dana lọjọbọ lo n se ọpẹ pe ori ko wọn yọ lọwọ ewu nigbati ilẹkun iwaju baalu B45 to ko awọn ero lati ilu Eko lọ si Abujas sadede fo yọ ni kete ti baalu naa balẹ tan nilu Abuja.