Ọgbẹni Cosmas Oni sọrọ lori Ibo ijọba ibilẹ nipinlẹ Ọyọ

Ọgbẹni Cosmas Oni sọrọ lori Ibo ijọba ibilẹ nipinlẹ Ọyọ

Agbẹnusọ fun ajọ to n se kokari eto idibo ijba ibilẹ nipinlẹ Ọyọ, OYSIEC, Ọgbẹni Cosmas Oni ti fidi rẹ mulẹ pe, ọjọ isẹgun ni ajọ naa yoo kede afikun ọjọ fawọn ẹgbẹ oselu lati seto ibo abnu wọn.

O ni lẹyin eyi ni wọn yoo mu orukọ awọn oludije ti wọn ba dibo yan fun ajọ OYSIEC ati pe ajọ naa ko ni ohunkohun se pẹlu orukọ awọn oludije ẹgbẹ oselu.