Ẹ wo fidio bi oṣiṣẹ Jamb ṣe sọ wipe ejo gbe 36m naira mi

Ẹ wo fidio bi oṣiṣẹ Jamb ṣe sọ wipe ejo gbe 36m naira mi

Laipẹ yi ni Philomena Chieshe sọ fun awọn oloyẹwe owo wo to wa sisẹ ni ọọfisi ajọ Jamb to wa nilu Makurdi, nipinlẹ Benue pe ejo abami kan lo gbe owo to to miliọnu mẹrindinlogoji naiara mọ oun lọwọ.

O ni ọmọ ọdọ oun lo jẹwọ nibi adura kan pe oun ni oun wa nidi ọrọ oun ti ejo fi n poora owo mọ oun lọwọ.

Ileesẹ itẹwe iroyin THE SUN lo ni fidio yi.