Ọti lile ko ni anfaani f‘ara

Ọti lile ko ni anfaani f‘ara

Dokita onisegun oyinbo kan, Adekunle Obilade ti gba awọn araalu nimọran lati ta kete sawọn ọti lile ti wọn nta ninu awọn ike kekeke lẹba oju popo.

Dokita Obilade kede bẹ́ẹ lasiko to n ba ileesẹ BBC sọrọ nipa bi awọn eeyan kan se ko asa tita ọti lile sara ni afẹmọjumọ, ọsan gangan ati ni alẹ.

O ni awọn ti lile kekeke yi maa nba ẹdọ-ki jẹ ni, to si tun maa nfa atọgbẹ ati ẹjẹ riru.

Dokita Obilade wa gbawọ̀n eeyan nimọran pe ki wọn dkun mimu awọn ọti lile yi nitoripe ta ara ni wọn j.