Odumakin: awọn alagbara lo wa lẹyin ijinigbe Dapchi

Agbẹnusọ fun ẹgbẹ naa, Yinka Odumakin sọ fun BBC Yoruba ninu ifọrọwanilẹnuwo wipe ohun ti o ba jọ ohun ni a fii we ohun, nitoripe ọrọ naa jọ ti awọn ọmọ ti wọn jigbe ni ilu Chibok nipinlẹ Borno ni ọdun 2014.