Buhari gbọ Faari

Aarẹ Buhari ni oko rẹ̀ nilu Daura Image copyright @MBuhari
Àkọlé àwòrán Buhari gbọ faari

Fun ọpọ to n fi oju arugbo ti ko gbọ faari wo Aarẹ Muhammadu Buhari, Aarẹ Buhari niyi ni oko rẹ nilu Daura nibi to ti wọ bata ọsọ igbalode trainers lọ si oko rẹ.