BBC Yoruba beere itumọ 'Staircase' ni Yoruba
BBC Yoruba beere itumọ 'Staircase' ni Yoruba
BBC Yoruba lọ si igboro lati beere itumọ 'Staircase' ni Yoruba lọwọ awọn araalu.
Nitori pe a ko fẹ ki ede Yoruba parun la ṣe n ṣeto " Bawo ni iwọ ṣe gbọ Yoruba to?'
Àkàsọ, Àkàbà àti awọn ọrọ miran ni eti BBC gbọ loni lẹnu awọn ti a fọrọwa lẹnu wo
Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si: