Olootu ijọba Germany bura fun saa kẹrin

Angela Merkel nsebura nile asofin Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Aarẹ Frank-Walter Steinmeier lo ti kọkọ yan Merkel ko to di pe o sebura nile asofin kekere

Olootu ijọba orilẹede Germany , Angela Merkel sebura lọjọru nile asofin orilẹede naa, eyi to fi nsefilọlẹ saa isejọba kẹrin lori aleefa ni orilẹede ti ọrọ aje rẹ gbooro julọ nilẹ Yuroopu.

Awọn asofin orilẹede Germany lo yan-an pada pẹlu ibo ọtalelọọdunrun ati mẹrin, ti ibo alatako rẹ si jẹ okolelọọdunrun o din marun, nigbati awọn asofin mẹsan ko dibo.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si:

Aarẹ Frank-Walter Steinmeier lo ti kọkọ yan Merkel ko to di pe o sebura nile asofin kekere.