Njẹ asiri akọsilẹ nipa rẹ bo lori Facebook?

Njẹ asiri akọsilẹ nipa rẹ bo lori Facebook?

Cambridge Analytica, ileeṣẹ ti atotonu nipa lilo akọsilẹ awọn eeyan lori Facebook sẹ si l’ọwọ ti da oludari rẹ, Alexander Nix, duro.

Ninu fidio kan ti wọn ka ni kọlọfin, o da bi ẹni pe Ọgbẹni Nix tọka si iru ọgbọn ti ileesẹ rẹ le lo lati ba awọn oloselu l’orukọ jẹ lori ẹrọ ayelujara.

Sugbọn, Cambridge Analytica sọ wipe iroyin naa ko sọ otitọ nipa ibaraẹnisọrọ ti wọn ka ninu ẹrọ kamera naa. Nnkan ti a mọ niyi.