Òǹkọrin kò gbọdọ̀ fòyà láti sọ òdodo
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Túnbọ̀sún Ọládàpọ̀: Òǹkọrin ni etí Ọba láti sọ òdodo

Olóyè Ọlátúnbọ̀sún Ọládàpọ̀ ti gba àwọn Òǹkọrin nílẹ̀ Yorùbá nímọ̀ràn láti máa sọ òdodo nípa ibi tí ìsèjọba kù sí.

Bákannáà ló rọ̀ wọ́n láti máse gba owó lọ́wọ́ ẹnìkan, máa fi bú ẹnìkejì nítorípé Yorùbá kìí wùwà báun.

Ó tún wá rọ àwọ̀n ọmọ ilẹ̀ Yoòbá pé ire ati ibi ló wà nínú isẹ́ tí wọn yàn ní ààyò, nítorí náà, wọn kò gbọdọ̀ máa pa isẹ́ kan tì bọ́ sí òmíràn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: