Ìsẹ́yìn: Ilé aṣọ òkè alárà ǹ barà

Ìsẹ́yìn: Ilé aṣọ òkè alárà ǹ barà

Yorùbá máa ń kọrin pé ‘ká ránmọ lásọ, Ìsẹ́yìn ni kò hunsọ, aṣọ tí a ró...’

Èyí fihàn wá pé Ìlú Ìsẹ́yìn, tó wà ní agbègbè Òkè Ògùn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ni wọ́n ti ń hun aṣọ̀ òkè pupọ julọ nile Yoruba.

BBC Yorùbá fẹsẹ̀ kan dé Ìlú Ìsẹ́yìn láti mọ̀ bí okoòwò aṣọ òkè se ń lọ sí, a sì ri pé ibẹ̀ gangan nilé aṣọ òkè alárà ǹ barà nítòótọ́.

A rí Sányán, Ẹtù, Àláárì, Alábẹ àtàwọn aṣọ òkè ìgbàlódé tó jẹ ojú ní gbèse.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: