Winne aya Mandela - Ó dìgbà

Èyí ni ìtàn ráńpẹ́ nípa ìgbésí ayé akọni obìnrin nnì lórílẹ̀èdè South Africa, Winne Mandela, tó di olóògbé.

1936

 • Ọjọ kẹrindinlọgbọn oṣu Kẹsan
  Aworan Winnie Mandela

  Wọn bi arabinrin Madikizela-Mandela nilu Bizana, Transkei (Eastern Cape).

1957

 • Aworan Winnie Mandela

  Oṣiṣẹ ilu naa to jẹ ọdọ pade Nelson Mandela, to jẹ amofin ati gbajugbaja alatako iṣejọba awọn alawọ funfun. Wọn ṣegbeyawo lẹyin ọdun kan.

1964

 • Aworan Winnie Mandela

  Wọn ran ọgbẹni Mandela lọ si ẹwọn gbere. Abilekọ Madikizela-Mandela polongo fun idasilẹ rẹ lai kaarẹ, o si di alatako fun iṣejọba awọn alawọ funfun.

1969

 • Aworan Winnie Mandela

  Wọn ju s'ẹwọn, o si lo ẹẹdẹgbẹta ọjọ din mẹsan latimọle.

1977

 • Aworan Winnie Mandela

  Wọn le abilekọ Madikizela-Mandela lọ si Brandfort, ilu kereje kan lẹkun Free State, fun bi ọdun mẹwa.

1986

 • Aworan Winnie Mandela

  Abilekọ Madikizela-Mandela sọ ọrọ apilẹkọ kan to da wahala silẹ, ni bi to ti fi ontẹ lu "ẹgba ọrun", fifi taya kọ awọn ti wọn furasi pe wọn lọwọ ninu iṣejọba asiko naa lọrun, ti wọn si tun n dana sun wọn. O ni, "Ninu iṣọkan, pẹlu iṣana ati ẹgba ọrun wa, ao sọ orilẹede yii di ominira."

1990

 • Aworan Winnie Mandela

  Ọgbẹni Mandela gba ominira kuro l'ọgba ẹwọn lẹyin ọdun mẹtadinlọgbọn. Abilekọ Madikizela-Mandela duro lẹnu iloro lati ki kaabọ.

1991

 • Aworan Winnie Mandela

  Wọn fi ẹsun ijinigbe ati ifiyajẹni kan an nipa ọmọ ọdun mẹrinla kan, Stompie' Seipei. Awọn ẹṣọ alaabo rẹ fi tipatipa mu Moeketsi ni 1989, ti wọn si pada ri oku rẹ. Abilekọ Madikizela-Mandela ni oun ko jẹbi iwa buburu kankan. Ṣugbọn wọn fidirẹmulẹ pe o jẹbi, wọn si dajọ ẹwọn ọdun mẹfa fun, botilẹjẹpe wọn yii pada si owo itanran.

1993

 • Aworan winnie Mandela

  Wọn dibo yan an gẹgẹ bi aarẹ ẹgbẹ awọn obinrin nilẹ Afrika. Wọn tun pada dibo yan an ni 1997.

1994

 • Aworan Winnie Mandela

  Wọn yan an gẹgẹ bi igbakeji minisita fun iṣẹ Ọna, Aṣa, Sayẹnsi ati imọ Ẹrọ. Wọn gba iṣẹ lọwọ rẹ nigba ti awọn ẹsun iwa ijẹkujẹ dide si.

1996

 • Aworan Winnie Mandela

  Lẹyin igbeyawo ọdun mejidinlogoji, tọkọ-taya naa tuka.

2003

 • Aworan Winnie Mandela

  Wọn dajọ ẹwọn fun nitori ẹsun jibiti ati ole jija lori owo to ya nile ifowopamọ. Wọn pada f'oju fo ẹsun ole jija naa, ṣugbọn o gba idajọ ẹwọn ọdun mẹta ataabọ fun ẹsun jibiti.

2007

 • Aworan Winnie Mandela

  Bi o tilẹjẹpe wọn pada yan an s'ile igbimọ aṣofin, o jẹ gbajumọ laarin awọn talaka, awọn ọmọ South Africa to jẹ alawọ dudu, ati awọn ọdọ.

2018

 • Ọjọ keji, oṣu Kẹrin
  Aworan Winnie Mandela

  Lẹyin aisan ọlọjọ pipẹ, Winnie Masikizela-Mandela fọwọrọri ku.

Ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rin ni Winne Mandela lò lókè èèpẹ̀, kí ọlọ́jọ́ tó dé lọ́jọ́ ajé, ọjọ́ kejì, osù kẹrin ọdún 2018 lásìkò àìsàn ọlọ́jọ́ gbọọrọ.

Ọjọ́rú,ọjọ́ kẹrìnlá osù kẹrin ọdún 2018 sì ló wọ káà ilẹ̀ sùn.

Winne Madikizela aya Nelson Mandela, sùn ùn re o.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Related Topics