Irú Kọ́mú wo lò ń lò?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Àwọ̀tẹ́lẹ̀: Èwo lo ní ìfẹ́ sí nínú orísirísi kọ́mú yìí?

Ǹjẹ́ ìwọ mọ kọ́mú tí wọn ń pè ní foamless, spacer, plunge, strapless, backless àti clap in front?

Arábìnrin Olúwaseun Táyọ̀ Balógun, tó jẹ́ onísòwò àwọ̀tẹ́lẹ̀ obìnrin sàlàyé lórí orísirísi kọ́mú tó wà lọ́jà báyìí àti àsìkò tí a leè lò wọ́n.

Bákanáà ló tún sọ nípa àwọn kọ́mú tó ní fùkẹ̀fùkẹ̀ (Foam) nínú àti àwọn èyí tí kò ní, àwọn tó lápá àti àwọn èyí tí kò ní pẹ̀lú irúfẹ́ asọ tí a leè wọ̀ wọ́n sí.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Related Topics