Èrò àwọn ènìyàn lórí ẹ̀rọ àyélujára nípa ìdámẹ́wàá sísan

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Kí la tún gbọ́ nípa ìdámẹ́wàá?

Laipẹ́ yii, olusọ̀aguntan ijọ RCCG, pasitor Adeboye sọ ni gbangba fun awọn ọmọ ijọ rẹ̀ wipe, ẹni ti ko ba san idamẹwa ko ni lọ si ọ̀run.

Ẹ o ranti wipe, ọrọ ti nja rain rain tẹ́lẹ̀ lori pe Daddy Freeze fesi si ọ̀rọ̀ pasitọ̀ Adeboye lori sisan idamẹ́wa leyii ti Freeze fesi pe idamẹ́wo ko pọn dandan.

Latari eyi lori ẹ̀rọ ayelujara, awọn eniyan tun fesi lori eyi to sẹ̀ jẹ jade latẹnu pasitọ Adeboye.

Àkọlé àwòrán "Idamẹwa ko wa fun gbogbo eniyan"
Àkọlé àwòrán Ẹ o waasu ọrun mọ ni?
Àkọlé àwòrán Kílódé tó jẹ́ pé ìdámẹ́wàá nìkan ni wọ́n n rí tọ́ka sí?

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: