‘Àìtó ọlọ́pàá ló mú kí olè ja Ọ̀ffà’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọlọ́fà: A ti ń kọ́lé fún ọlọ́pàá kògbérégbè

BBC Yoruba de ìlú Ọ̀ffa láti mọ ipò tí ìlú náà wà lẹ́yìn ìsẹ̀lẹ̀ adigunjalè tó gba ẹ̀mí ọ̀pọ̀ ara ìlú àti ọlọ́pàá.

Nígbà tó ń bá wa sọ̀rọ̀, Ọlọ́fà tìlú Ọ̀ffà ní àìtó ọlọ́pàá ló mú kí olè ja Ọ̀ffà sùgbọ́n àwọn ti ń kọ́lé fún ọlọ́pàá kògbérégbè tíjọba fẹ́ kó wá sí ìlú náà.

Bákan náà la ba àwọn èèyàn tó forí sọta ìsẹ̀lẹ̀ adigunjalè náà sọ̀rọ̀ àti agbẹnusọ fún ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara lóríi ìsẹ̀lẹ̀ adigunjalè náà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: