Sẹ́nétọ̀ Nàìjíríríà tó ń lo ayédérú ìwe ẹ̀rí
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

NUC: 'Ayédèrú n'ìwé ẹ̀rí sẹ́nétọ̀ Foster'

Sẹ́nétọ̀ Ogola tó ti ń sàfihàn àseyọrí ìwé ẹ̀rí tó sì ti ń lò ó fún pàtàkì òsèlú rẹ̀.

Sùgbọ́n ní báyìí, ìwádìí fi hàn pé àwọn ìwé ẹ̀rí oyè Phd tó gbà nínú ìmọ̀ adarí krìstẹ́nì èyí tó gbà láti fásitì tí àjọ NUC kò fọwọ́ sí jẹ́ ayédèrú.