Àwọn ohun èèlò tí Awọ́lọ́wọ̀ lò gbẹ́yìn
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọkọ̀ Awólọ́wọ̀ yìí ti lọ yíká Nàíjíríà

Lẹ́nu àbẹ̀wò BBC Yorùbá sí ilé Awólọ́wọ̀ ní Ìkẹ́nnẹ́, a rí asọ tó kú sínú rẹ̀, awò ojú rẹ̀, aago ọwọ́, owó ẹyọ àti owó bébà àtijọ́ tó ná kù, tó fi mọ́ ọkọ̀ tó fi lọ yíká Nàíjíríà láti se ìpolongo ìbò ààrẹ ní ọdún 1979 àti 1983.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Related Topics