Ọlọ́pàá kan rèé tí kìí gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Adédèjì: Ìse ilé ló gbé ọlọ́pàá tó ń gba rìbá dé ìta

Adéwọlé Adédèjì Julius jẹ́ agbẹjọ́rò, tó sì tún jẹ́ ọlọ́pàá tí kìí gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀.

Òkìkí Adédèjì tìí tàn yíká ilẹ̀ yìí àti òkè òkun, tí wọn sì fún un ní àmì ẹ̀yẹ ọlọ́pàá tó pegedé jùlọ ní Nàíjíríà.

Ó wá rọ ìjọba láti sètọ́jú àwọn ọlọ́pàá dáadáa bí wọn kò bá fẹ́ kí wọn máa gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: