‘Ọga ọlọpaa lasẹ lati kọ ipe awọn asofin’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kayọde Ajulọ; Bi Ile asofin se pe igba rẹ , ni wọn se ba pe e

Amofin agba kan lorilẹede Naijiria, Kayode Ajulọ ni ofin to de ile-isẹ ọlọpaa ti Naijiria, sọ wi pe ko pọn dandan fun ọga ọ̀lọpaa o yoju si ile asofin lẹyin ti o ti ran igbakeji rẹ lati soju rẹ.