Ọ̀pọ̀ àwọn tó ńlo ògùn Codein ló sún mọ̀ wa bí etí.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kò tún yẹ ká máa gbé ògùn gba ẹ̀yìn yọ

Adéyẹmí Olúwatósìn tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn apoògùn orílẹ̀èdè Nàìjíríà tẹnu mọ̀ ohun tí ìjọba Nàìjíríà tún lè se sí àwọn tó ń gba ẹ̀yìn po ògùn Codeine.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: