Agbejọ́rò àádọ́ta wà níbẹ̀ láti ràn ọ́ lọ́wọ́ fún òmìnira rẹ

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionAgbejọ́rò wà níbẹ̀ láti ràn ọ́ lọ́wọ́ fún òmìnira rẹ

Gbogbo ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ló wà nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ yìí.

Mọ ẹ̀tọ́ rẹ gẹ́gẹ́ bíi ọmọ Nàìjíríà gidi.

Ó jẹ́ ọ̀nà àbáyọ sí kíkọlu ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn.

Fi ọwọ́ tẹ ìmọ̀ ẹ̀rọ 'mọ ẹ̀tọ́ rẹ' kí orí òmìnira láìṣe ojúùṣájú.

Kò yẹ kí o fi ara rẹ jìyà mọ́, ló ìmọ̀ ẹ̀rọ yìí bí o ti yẹ

Adeola Akande ló ṣe èròjà ìmọ̀ ẹ̀rọ 'mọ ẹ̀tọ́ rẹ' gẹ́gẹ́ bíi ọ̀nà àbáyọ síìṣoro kíkọlu ẹ̀tọ́ ọmọ Nàìjíríà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: