Mọ ẹ̀tọ́ rẹ gẹ́gẹ́ bíi ọmọ Nàìjíríà gidi
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Agbejọ́rò wà níbẹ̀ láti ràn ọ́ lọ́wọ́ fún òmìnira rẹ

Gbogbo ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ló wà nínú app yìí.

Fi ọwọ́ tẹ ìmọ̀ ẹ̀rọ 'mọ ẹ̀tọ́ rẹ' kí orí òmìnira láìṣe ojúùṣájú.

Adeola Akande ló ṣe èròjà ìmọ̀ ẹ̀rọ 'mọ ẹ̀tọ́ rẹ' gẹ́gẹ́ bíi ọ̀nà àbáyọ síìṣoro kíkọlu ẹ̀tọ́ ọmọ Nàìjíríà.