'Ẹni tó pé, ó yẹ kó sisẹ́'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Sunday Sobàtà: Mò ń fi isẹ́ mi pe àwọn abarapa níjà láti mase ya ọ̀lẹ

Sunday Sobàtà pe àwọn tó lọ́wọ́ àtẹsẹ̀ níjà láti ma ya ọ̀lẹ, to si ni isẹ sobata ti oun n se yii ni oun fi n jẹ lai se agbe gẹgẹ bi awọn abarapa ti maa n se.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: