JJ Omojuwa gbà olósèlú nímọ̀ràn lórí ìbò 2019
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Omojuwa: Olùdíje ní 2019 gbọdọ̀ setán láti ná owó gidi

Onímọ̀ nípa ẹ̀rọ ayélujára, Japhet Omojuwa sàlàyé ipa tí ẹ̀rọ ayélujára leè kó nínú ìdìbò ọdún 2019 ní Nàìjíríà.

Bákan náà ló sọ pé, àwọn olùdíje náà gbọdọ̀ bẹ̀bẹ̀ fún ìbò, kí wọn tó leè borí.

Ó tún mẹ́nu bàá pé yóò dára káwọn olósèlú alátakò gbé olùdíje kan soso kalẹ̀ kí wan tó leè na Buhari.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: