Ọbẹ̀ àjẹpọ́nnulá ni ẹ̀fọ́ rírò
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ẹ̀fọ́ rírò jẹ́ alábárìn iyán, fùfú, ẹ̀bà, àmàlà àti ìrẹsi funfun

Ayokunle Chef Khen lo ro ẹ̀fọ́ fún BBC Yoruba lọsẹ yìí.

Oríṣíi ẹ̀fọ́ bíi tẹ̀tẹ̀, ewúrò, gbúre, amúnútutù, wọ̀ọ̀rọ̀wọ̀, ṣọkọ, ìgbá, úgú, elégédé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ló wà.

Pọ̀ńmọ́ ìjẹ̀bú, ata rodo, àlùbọ́sà, ẹja panla, irú (wooro tábì pẹ̀tẹ̀), epo pupa, ògúnfe, ìgbín àti iyọ̀ ni Ayokunle fi se ẹ̀fọ́ rírò tòní.

Ẹfọ́ ríro máa ń máradàgbà, o ń jẹ́ ki ara ẹni dán dáadáa

Eyin náà, ẹ dan an wò nile fún ẹbi yin.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: