Aborisade:  Ọ̀rọ̀ Obasanjo gba ìfunra o
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Aboriṣade: Mẹ̀kúnnù gbọ́dọ̀ fura sí Obasanjọ

Agbẹjọ́ro ati ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ enìyàn, Femi Aborisade, ti kilọ fun awọn ọmọ Naijiria latari pe, Aare ana, Oloye Olusegun Obasanjọ, ti da ẹgbẹ alajumọse rẹ̀ pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òsèlú ADC.

O ni Obasanjo kii ṣe olugbala awọn mẹ̀kúnù o.