Onímọ̀ sáyẹ́ǹsì: ẹ̀jẹ̀ níi ṣe pẹ̀lú ara sísan

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionOúnjẹ níwọ̀nba lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti má sanra púpọ̀

Jíjẹ oúnjẹ tó dára àti ṣíṣe eré ìdárayá lè dín ara sísan rẹ kù

Ẹjẹ̀ ní i ṣe pẹ̀lú bi o ṣe maa ríran sí.

Ounjẹ ọlọra máa ń mú ni sanra síi ni fún ìdí èyí Oúnjẹ níwọ̀nba lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti má sanra púpọ̀.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Jíjẹun ni alẹ́ kìí tètè dà, ó máa ń ṣòro láti dà níkùn ni alẹ́.

Àkọlé àwòrán Oúnjẹ ọlọra máa ń jẹ́ ki èèyàn sanra síi

Sísá fún ìpápánu máa ń dín ara sísan kù ni.

Iwádìí sáyẹǹsì fihàn pe irú oúnjẹ ti ò ń jẹ níi ṣe pẹ̀lú òdiwọ̀n ìwọ̀n ara rẹ ni kílò.

Àkọlé àwòrán Oúnjẹ kìí tètè dà lálẹ́

Àwọn onímọ̀ sayẹnsi ti le fa ọ̀rá ara kúrò pẹlu iṣẹ́ abẹ.