Ṣọ́ra fún irú oúnjẹ ti ò ń jẹ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Oúnjẹ níwọ̀nba lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti má sanra púpọ̀

O leè jogún ara sisan láti ọdọ òbí rẹ̀.

Àwọn onímọ̀ sayẹnsi ti le fa ọ̀rá ara kúrò pẹlu iṣẹ́ abẹ.

Jíjẹ oúnjẹ tó dára àti ṣíṣe eré ìdárayá lè dín ara sísan rẹ kù.

Ẹjẹ̀ ní i ṣe pẹ̀lú bi o ṣe maa ríran sí.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àsìkò ti ò ń jẹun àti irú ouńjẹ ti ò ń jẹ nii ṣe pẹ̀lú ara sísan, èyí tó lè jẹ́ àjogúnbá nínú ẹbí.

Jíjẹun ni alẹ́ kìí tètè dà, ó máa ń ṣòro láti dà níkùn ni alẹ́.

Àkọlé àwòrán Oúnjẹ ọlọra máa ń jẹ́ ki èèyàn sanra síi

Sísá fún ìpápánu máa ń dín ara sísan kù ni.

Iwádìí sáyẹǹsì fihàn pe irú oúnjẹ ti ò ń jẹ níi ṣe pẹ̀lú òdiwọ̀n ìwọ̀n ara rẹ ni kílò.

Àkọlé àwòrán Oúnjẹ kìí tètè dà lálẹ́