Èkìtì: Àwọn elétò ìdìbò ńka ìbò ní ìrọwọ́rọsẹ

Àkọlé àwòrán Àwọn eléto ìdìbò n ka ìbò

Ìbò kika ti ń lọ níbi Eto ìdìbò abele, láti yan oludije fún ipò Gómìnà lábẹ́ asia ẹgbẹ́ òṣèlú APC nipínlẹ̀ Ekiti.

Lẹ́yìn tí ètò ìdìbò parí ní àwọn elétò ìdìbò bẹ̀rẹ̀ ìbò kíkà

Àkọlé àwòrán Ìbò kika ti ń lọ níbi Eto ìdìbò abele, láti yan oludije fún ipò Gómìnà

Tanko Al-Makura lo kede ìbẹ̀rẹ̀ yíyọ àti kíkà ìbò, láti mọ ẹni tí yóò jáwé olúborí

wọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Awọn ti ètò ìdìbò náà sojú, sọ pé etò náà kò lọ ní ìrọwọ́rọsẹ̀ nìkan bíkò ṣe pé kò sí màgòmágó kankan níbẹ̀.

Ẹ̀wẹ̀ Sunday Balogun ló jáwé olú borí níbi ìdìbò abẹ́le fún ẹgbẹ́ òṣèlú MPN (Mega Party of Nigeria) ní ìpínlè Èkìtì láti sojú ẹgbẹ́ náà nínú ìdìbò Gómìnà tí yóò wáyé ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kèje.

Image copyright BBC Sport
Àkọlé àwòrán Etò idibo náà lọ ní ìrọwọ́rọsẹ láì ní màgòmágó nínú