Mọ iye ọdún tó ṣeéṣe kí o lò láyé

Njẹ́ o mọ̀ pé iye ọdún tó ṣeéṣe kí gbogbo ènìyàn yóò lò láyé ti fi ọdún méje pọ̀ si láti 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè tí o ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.