Gómìnà Ọ̀ṣun: àgbájọ ọwọ́ la fí ń sọyà

Àwọran Aregbesola Image copyright Aregbesola/twitter
Àkọlé àwòrán Arẹgẹṣọlá jẹ́jẹ̀ láti máa fi ìpínlẹ̀ Ọṣun sílẹ̀ lẹ́yìn sáà rẹ̀

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Ọ̀gbẹ́ni Rauf Arẹgẹṣọlá tí jẹ́jẹ̀ pé òun koò ní fi ìlú sílẹ̀ lẹ́yìn sáà òun.

Arẹgẹṣọlá jẹ́jẹ̀ ọ̀hún lásìkò tó ń ṣètò ìfọ̀rọ̀wérọ̀ níbi ìpàde kan lónìí n'ípinlẹ̀ Ọ̀sun.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ò ní ìpinu òun láti ṣè èyí ni kí òun baà le ran 'ẹni tí yóò gba ipò ẹ́yìn òun lọ́wọ́, kí gbogbo iṣẹ́ tí òun ti ṣe má baà dìbàjẹ́.

Ọ̀gbẹ́ni Arẹgẹṣọlá sọ pé, lẹ́yìn tí òun bá fi ipò sílẹ̀ ní ìlànà òfin nínú oṣù kọkànlá ọdún yìí, ó ṣe pàtàkì láti ṣe atọnà fún ẹni to n bọ̀ lẹyìn