‘Tunde Kelani yan mi jẹ lori fiimu ‘Toluwanilẹ’

‘Tunde Kelani yan mi jẹ lori fiimu ‘Toluwanilẹ’

Lopin ọsẹ ni Iwe Iroyin kan ni Baba Wande fẹsun kan Tunde Kelani wipe owo to tọ si oun, ko ni wọn fun oun lori fillmu naa ti o si jẹ wipe oun lo kọ itan naa.