Ọ̀gá Bello dárò ikú Aisha Abimbọla
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọ̀gá Bello: Ikú Aisha Abimbọla ká wa lára

Ìròyìn kan tó gbalẹ̀ kan ní ọjọ́rú lórí ìtàkùn àgbáyé ní ìlúmọ̀ọ́ká òsèrè tíátá obìnrin kan, Aisha Abimbọla ti mí kanlẹ̀.