Akójọpọ̀ àwòrán Aisha Abimbọla
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọmọge Campus, ó dàárọ̀ o

BBC Yoruba se idaro ìlúmọ̀ọ́ká òsèrè tíátá obìnrin, Aisha Abimbọla, pẹlu akojọpọ oniruuru aworan to rẹwa to ya lasiko to wa loke eepẹ.

Ilu Canada ni Aisha Abimbọla ti ọpọ eeyan mọ si ọmọge Campus ti mí kanlẹ̀.lati ipasẹ aisan jẹjẹrẹ to n baa finra.

Gbogbo wa ni BBC Yoruba gbaa ni adura pe, ki Ọlọrun tẹẹ si afẹfẹ rere.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: