Ìjọ Àgùdà: Kò dára ká máa ké gbàmí-gbàmí kiri lójoojúmọ́

BBC Yoruba wà ní Ìkẹjà ní ìlú Èkó níbi tí àwọn ọmọ ìjọ Àgùdà ti se ìwọ́de, tí wọn sìń gbarata lórí ìsẹ̀lẹ̀ ìsekúpani tó ń wáyé ní ojoojúmọ́ ní orílẹ̀èdè Nàíjíríà.

Wọn wá rọ ìjọba àpapọ̀ láti tètè fòpin sí ìtàjẹ̀sílẹ̀ ojoojúmọ́ yìí.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: