Àjẹpọ́nnulá fún tòní ti dùn jù, gbìyànjú láti sè é nílé

Ẹfọ rírò lọ́nà ìgbàlódé dùn láti fi jẹ iṣu.

Chef Michael Elegbede lo se ọbẹ àjẹpọ́nnulá fun BBC Yorùbá loni.

Àwọn èròjà ti o nílò wà ni àrọ́wọ́tó rẹ.

Gbìyànjú láti sè é fún àwọn ará ilé rẹ lópin ọ̀sẹ̀ yìí ki wọn jẹ àjẹpọ́nnulá ọbẹ̀ tó dùn.

Ẹja èpìyà, epo, irú, edé gbígbẹ, àlùbọ́sà, áyù, ẹtalẹ̀, tàtàṣé, ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀ àti rodo ni àwọn èròja ti o nilo lati fi rò ẹfọ rẹ ki o le fi gbadun iṣu sísè.

Awọn èròjà aṣaralóore pọ ninu ọbẹ ẹfọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Alase wa gbamọran pe ki ẹ fi ara balẹ wo ojú ẹja epiya ti ẹ fẹ ra pe ara rẹ ń dán, oju rẹ mọ́ rkekete